Ololufe (Refix|Explicit)歌词由Olumide演唱,出自专辑《Ololufe (Refix) [Explicit]》,下面是《Ololufe (Refix|Explicit)》完整版歌词!
Ololufe (Refix|Explicit)歌词完整版
It has been years now, You've gone so far from me
And I miss you so, Why you're not looking back
Igbawo lo ma wale, Igbawo lo n pada bo wa
Ma foju mi s'ona Olomi
Ololufemi, N'ibo lo wa oo
Ayo Okan mi, N'ibo lo lo (N'ibo lo lo)
Orekelewa t'eminikan, N'ibo lo wa oo
Mo n s'aferi re, Wale o, yara rowa o
Erin nbe nigbo, kato fi Kinihun joba
O w'oluwa l'okan, lo diri ewa f'akuko
Eduwa f'ife re simi l'okan, oni n ma bayi o
Ko si bo se le peto oo, iwo n'moyan o
Tori Aye leyi orun leyi, Ifemi o yi o
Ojo le ro Orun le ran o, Iwo n mo yan o
I will come through the wild, through the vally, around the world
I'm coming for you, baby ma wo e wale ooo o
It has been years now, You've gone so far baby
And I miss you so, Why you're not coming home
Igbawo lo ma wale, Igbawo lo n pada bo wa
Ma foju mi s'ona Olomi
Ololufemi, N'ibo lo wa oo
Ayo Okan mi, N'ibo lo lo (N'ibo lo lo)
Orekelewa teminikan N'ibo lo wa oo
Mo n s'aferi re, wale o, yara rowa o
Ololufemi, Nibo lo wa oo
Ayo Okan mi ye, N'ibo lo lo (N'ibo lo lo)
Orekelewa teminikan N'ibo lo wa oo o
Wale o, wale o
Ololufemi, N'ibo lo wa oo (ooo ooo)
Ayo Okan mi oo oo, baby o (N'ibo lo lo)
Orekelewa mio, Orekelewa mio, rowale baby oo
Ro Wale o, wale o