So Fun Jesu歌词由Success Ajayi演唱,出自专辑《Mighty-Mighty!》,下面是《So Fun Jesu》完整版歌词!
So Fun Jesu歌词完整版
Are mu O, okan re poruru
So fun Jesu, so fun Jesu
Ibanuje dipo ayo fun O?
So fun Jesu nikan
So fun Jesu, So fun Jesu
On l‘ore ti o mo
Ko si ore tabi ‘yekan bi Re
So fun Jesu nikan
Asun-dekun omije lo nsun bi?
So fun Jesu, So fun Jesu
Iwo l‘ese ti enikan ko mo?
So fun Jesu nikan
So fun Jesu nikan
So fun Jesu, So fun Jesu
On l‘ore ti o mo
Ko si ore tabi ‘yekan bi Re
So fun Jesu nikan
Iwo nfoya ‘banuje ti mbe bi?
So fun Jesu, So fun Jesu
Iwo saniyan ojo ola bi?
So fun Jesu nikan
So fun Jesu nikan
So fun Jesu, So fun Jesu
On l‘ore ti o mo
Ko si ore tabi ‘yekan bi Re
So fun Jesu nikan
Ironu iku nda o lamu bi?
So fun Jesu, So fun Jesu
O nsaferi ijoba Jesu bi?
So fun Jesu nikan
So fun Jesu nikan
So fun Jesu, So fun Jesu
On l‘ore ti o mo
Ko si ore tabi ‘yekan bi Re
So fun Jesu nikan