Eyi Owu Awi歌词由Olawale kayode演唱,出自专辑《Eyi Owu Awi》,下面是《Eyi Owu Awi》完整版歌词!
Eyi Owu Awi歌词完整版
Eyi owu awi
Ti oluwa nio se
Eyi owu awi
Ti olorun nio se
Bi okuku ba su birimu birimu
Bi enipe ile oni momo
Igbagbo mi ko ni ye
Ti olorun nio se
Ileri oluwa koni ye odami loju
Boti lewu ko pe to
Oro re koni ye
Koto da mi loti mo mi
Oti mo ohun ti maje
Bi esu nleri bi esu nhale ma debi ogo dandan
Emi ni wura iye biye ola sa loti pe mio
Ipe to pe mi ipe ire ni
Ma de bi ayo mio