Lodore歌词由Yomi Unusual演唱,出自专辑《Lodore》,下面是《Lodore》完整版歌词!
Lodore歌词完整版
Lilo Bibo mi dowore
Olorun anu
Iji to ja ko mayodomi
Edumare bami fasesi
Ki rogolo ki se orire
Imole tan sona mi
Kimasinrinlaye
Jekin layo dale
Kayemi dun koloyin
Oba alate anu
Ki anu fohun fun mi
Oba alayo ni o
Iri ko se saye mi
Ono mi la sireee
Koseni to wa sodo re e
To ba ekun looo
“Lodo re ni o
Ire ti san wa
Lodore ni o
Ayo ti san wa
Lodore ni o ire ti San wa
Lodore ni o igbala ti san wa……
Ire a wa lona mi
Ayo awa lodomi
Ibukun dapo Mo ogo
Ki radun kale
Imisi apo fun mi
Magbori le serere
Munumidun mayomi kun
Olorun alagbara
Sise rere laye mi
Mi o ni fayisan logba
Baba gbogun ebemi
Tori lodore ni motiwa
Oba alate anu
Marayese marogolo mi o ni seru egbe
Edumare bami fasesi
Lodore ni o
Ire ti sanwa
Lodore ni o ayo ti san wa
Lodore ni o ire ti san wa
Lodore ni o igbala ti san wa