Democracy歌词由Dagrin演唱,出自专辑《Democracy》,下面是《Democracy》完整版歌词!
Democracy歌词完整版
Corruption ti hit nation
Gbogbo wa la n live in desperation
Tori 'e n'mo se n drink medication
Fun protection against starvation pelu corruption
Tori generation yii, a need salvation
Through a strong constitution
Ninu studio, owo naa l'afi n book session
E joo e stop sensation
A need action ko n se prosecution
Free/Fair pelu alaafia ninu nation
E gbo nnkan ti mo fe so
eleyii 'o nse body vibration
(Clear throat)
Nigeria ni mo ti ri t'olopa ma n toro bara
Nitori twenty naira won le fi ba e faa ya!
Agbero maa n f'agidi gba Gala lowo driver
E'e ri nnkan kan se si, eyin ijoba e n kaalara
Gbogbo owo ti e ti gbe mi l'awon omo omo yin maa bi
E'e ri bi awon ara ilu se n pariwo: Ebi!
T'oba ri life ti talika n live ni Birnin Kebbi
Gbogbo yin patapata ni Olorun maa da l'ebi.
A'a ran omo lo si school, ko ni si textbook
E de promise pe e maa fun wa ni free education
Ki l'on je bee? Owo nla ma l'a fi n s'admission.
E de ti ko gbogbo awon omo ti yin kuro ninu nation.
A ti igba ti mo ti n ko'rin, mi o ni money
E'e tie ki n soro rara nipa music industry
Economically, agidi l'a fi n ra bread
Ta lo so wipe President o ki n fine ninu telly?
E'e mo ju ki e so'ro petrol, pelu football
A ti igba ti a de ti n gba World Cup, a'a gba cup.
O ga o! Boya gan an l'atie gba second.
Awon yen naa, won a maa play ball bi alakan.
Graduate maa maa wa'se, gbogbo bata e a je,
a'a ye s'egbe, everywhere ko si employment,
Eni ti o ti n kole tele, ko le ra cement,
Increase ni rent, decrease ni salary payment.
Shey democracy leleyii abi crazy demo?
Oluwa shaanu wa dakun ma ma je ka jego.
Ba'a laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin 'pe kee ma dibo.
Se democracy l'eleyi abi crazy demo?
Oluwa s'aanu wa dakun ma ma je k'a je'go.
Ba wa laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin wipe k'e ma d'ibo.
Awon eeyan n sise, won n gbe ninu ise,
Awon elo mii, nitori owo, won ti gb'ese.
Awon elomii n gb'owo ni ita, nitori won le ju ese,
Nigba to je awon ijoba gan an, won o p'ese ise.
Wo'a lo si university, wa se tan, waa gba pali,
Pelu pali re, wa tun maa wa'se ka kaakiri,
Gbogbo ibi ti o ba lo, won a ni kosi vacancies.
Gbogbo kini yen, o maa ma fun e ni headache.
Awon elomii n jale tori ko si ise ni igboro.
Economically, most obinrin ti di ashewo.
O ga o! Ko de 'n se ejo elomii ti e ba ro o.
Sugbon aso yellow ti di white, l'owo o lilo.
Ijoba, e wa na. (clears throat). E duro na.
O ga o. Eekan l'osu l'a ma n ni ina.
O n happen all over Nigeria, pelu Kaduna,
Minna, gbogbo yin ti e ba ilu je l'e maa gb'ina.
Aimoye titi ti o je'pe moto o le gba 'be.
Lo si under bridge l'Oshodi, gbogbo ibe ti baje.
Ti ojo ba ro, gbogbo ibe yen maa di kpenshen-kpenshen.
Ti o ba ya, a si maa gbe oko oju omi koja ni be.
Gbogbo promise ti e make, iro l'o wa n' be
Sebi eyin naa, e ma n travel lo si Yankee.
E'e ri bi titi won pelu economy won se ri?
Eyin kan n lo si be, e kan lo n se faaji!
Gbogbo nnkan l'awon ijoba yii fi ni wa l'ara.
Ko de ri bee nigba ti a koko gba ominira.
But nigba ti awon Big Bros ti take over,
Gbogbo owo wa patapata ni won fi n da agbada.
Nigeria, gbogbo wa l'a n fi ori f'aya
A t'omode a t'agbalaba, pelu t'oko t'aya,
Baba, mama, pelu awon omo mefa ma sun si inu yara
eyo kan. Bawo ni won o se ni maa l'alakala?
Shey democracy leleyii abi crazy demo?
Oluwa shaanu wa dakun ma ma je ka jego.
Ba'a laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin 'pe kee ma dibo.
Se democracy l'eleyi abi crazy demo?
Oluwa s'aanu wa dakun ma ma je k'a je'go.
Ba wa laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin wipe k'e ma d'ibo.
Awon eeyan maa n ni Nigeria, Giant of Africa,
Lo wo bi economy won se better ni South Africa.
Ghana celebrate ten years ti won ti ni ina, ti won o tan atupa.
Ti tiyin e'e mo ju ki e s'oge, ki e tun wo agbada.
Igba kan ni won maa n ko awon were l'oju titi,
awon were maa n rin kiri pelu awon eeyan gidi.
Ni isinyin, awon were, won o l'identity -
Local Government kan, o le pade were fifty.
Ki lo de? Awon olowo nikan lo n s'oge.
Awon omo yin, pelu awon iyawo nyin, won n gbe gele.
E n gbe fila. Democracy alagbada.
O ga o. Owo gbogbo wa l'e fin n yi ata.
National ID Card, owo l'a fi n register.
A o ri nnkan kan. E da passport wa pada.
E n waste time omode pelu agbalagba.
E se o. E ranti 'pe Olorun wa.
Igba ti a gbo National ID Card, inu wa dun.
Asee won n d'ogbon, won fe ki Oba wole.
Oba ti wole, agidi l'a fi n san'wo ile.
School ma n strike, ohun yen, se iyen la fe pe ni holiday?
E'e san owo awon osise, ranti pe awon naa l'omo n'le.
Awa l'a ni petrol, ki lo de ti petrol 'o flow?
E n gb'owo le e l'ojoojumo, ki lo se yin o?
Ti Olorun ba binu, gbogbo yin ni petrol maa jo.
Se democracy alagbada l'eleyii tabi shimi?
E ranti 'pe most people l'o te'ka fun yin
A'a le ra Maclean(s), pako l'a maa fi n fo eyin
Ki lo se yin? Eeyan sha l'awon Bill Clinton.
O'o le ji l'ojo kan, ki o so 'pe o fe je iyan.
Lai se ojo Sunday. Garri nikan gan an ti won.
Alagbara l'eni ti o ba ra rice De Rica kan.
O pay mi ki n kuro ni Nigeria, ki n sa lo si Abidjan.
Shey democracy leleyii abi crazy demo?
Oluwa shaanu wa dakun ma ma je ka jego.
Ba'a laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin 'pe kee ma dibo.
Se democracy l'eleyi abi crazy demo?
Oluwa s'aanu wa dakun ma ma je k'a je'go.
Ba wa laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin wipe k'e ma d'ibo.
Shey democracy leleyii abi crazy demo?
Oluwa shaanu wa dakun ma ma je ka jego.
Ba'a laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin 'pe kee ma dibo.
Se democracy l'eleyi abi crazy demo?
Oluwa s'aanu wa dakun ma ma je k'a je'go.
Ba wa laju awon ijoba ko to di quarter-to.
Mo de pariwo titi fun yin wipe k'e ma d'ibo.