Oba Ni O歌词由Olawale kayode演唱,出自专辑《Oba Ni O》,下面是《Oba Ni O》完整版歌词!
Oba Ni O歌词完整版
Oba ni o
Oba ni o
Laye atorun
Oba ni o
Oba ni o
Laye atorun
Leyin re ko ma si alagbara kankan
Leyin re ka ma si amoye kankan o
Oba ni o
Oba ni o
Laye atorun.
Imo re ga oju gbogbo aye
Imo re ga oju gbogbo eniyan
Agbara re ga oju gbogbo aye
Agbara re ga o ga
Oju gbogbo eniyan
Awamaridi eledumare Oba ayeraye.
Oba oba Oba
Oba ni Oba ni Oba ni o
Aditu nla olodu omo are
Ijinle ni o
Alaile tuwo
Oda aye atorun Lai si opo togbe duro
Iranlowo eda gbogbo
Gbani Gbani loo ogun le