Olorun Ajulo歌词由Olujimi Kush演唱,出自专辑《Olorun Ajulo》,下面是《Olorun Ajulo》完整版歌词!
Olorun Ajulo歌词完整版
Olorun ajulo o
Iwo l'ake pe
Jagunmolu o
Wa ba wa pe e
Dide ija s'eni to ni mi lara
Dide ija s'eni to nse elenini mi
Abatenije to loun o ba temi je
Panapana to loun o pa'na ogo mi
Adaniduro to fe dami duro
Afopin'na to fe pa fitila
Dide ija o (Dide ija)
Dide ija o (Dide ija)
Olorun Jakobu (Dide ija)
Dide ija o (Dide ija)
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Gbogun ti won awon to ngbogun ti mi
Gbemi leke awon to nse inunibini simi
Je ki won subu, je k'ona won su
Kara'ye le mo pe mo ni O ni Baba o
Gbogun ti won awon to ngbogun ti mi
Gbemi leke awon to nse inunibini simi
Je ki won subu, je k'ona won su
Kara'ye le mo pe mo ni O ni Baba o
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Ta ni 'wo oke ni waju Olorun Jakobu
Ki o di 'petele
Oke idaduro
Oke ifaseyin
Oke airo'mo bi, oke aisan
Ki o di 'petele
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi
Olorun to f'ajulo han Farao
F'ajulo han ogun aye mi