Baba Mimo Ade歌词由Ui演唱,出自专辑《Songs of Praise》,下面是《Baba Mimo Ade》完整版歌词!
Baba Mimo Ade歌词完整版
Baba mimo a de, awa s'iwaju re
Baba mimo ade a wa wo le fun o
Baba mimo ade, a tun wa ju' ba re
Dari ese waji wa ( Obalumona) gba (dari ji wa o)
Gba adura wa, ( oba Olupese)
Baba ran emimimo re si wa
K'o to wa s'o na, ki ibukun re oluwa k'o sokale wa
Solo: Baba mimo, gbadura wa
Wa f'ase si
Baba mo f'ase si
Baba mimo k'adura wa gba l'oruko jesu
Amin o