笨鸟先飞
我们一直在努力
2025-01-26 14:54 | 星期天

Kosi Cash歌词-Sambak&Vinnyio&Mickeyz

Kosi Cash歌词由Sambak&Vinnyio&Mickeyz演唱,出自专辑《Kosi Cash》,下面是《Kosi Cash》完整版歌词!

Kosi Cash歌词

Kosi Cash歌词完整版

bese biti jago,

ero yapa ninu bank bi eni to fewo danfo,

Oogu wa bi pondo, awon ball bi ronaldo

Awọn ijọba hi , wan ti ẹ funny gan

Lati 1960 lati fall in love

Wọn dẹ n gbe wa mọra , A dẹ n tẹlẹ wọn

Adẹ n tẹlẹ wọn Adẹ n tẹlẹ wọn

Buh o fresh sha , O Jẹ kama wise sha

Mọ nkan to n ṣe oo, Koma lọ bu Aisha

Garri ti wọn , Ati lọ Dubai o wọn

Kinṣe fun oru awa . Iyẹn fun awọn mọmọ

Kosi cash , Ko si fuel

Ijọba dẹ n gbowo lọ

Kosi cash , Ko si fuel

Isaja isaja , Kosi Chance

Kosi cash , Ko si fuel

Wọn wa n campaign fun wa

Kosi cash , Ko si fuel

POS gara tan

未经允许不得转载 » 本文链接:http://www.benxiaoben.com/efc3cVVA9BQpTVQsGDA.html

相关推荐