Gbonmire (Let me be)歌词由Lollaby演唱,出自专辑《Gbonmire (let me be)》,下面是《Gbonmire (Let me be)》完整版歌词!
Gbonmire (Let me be)歌词完整版
Ngbọn mi re témi yemi
O yé mi o ma yemi
É no matter oun eda le so
O yé mi o ma yemi ooo
Í yin mi nu' témi yemi
O yé mi ooo o yé mi
É no matter oun eda le so
To le wí ooo o yé mi o ma yé mi ooo
Verse 1
I remember when I just dey start
Trying to put some things together ko jọ ra wọn
Won fi mi se yeyé
Won fi mi s'awada
Won ni a o mo orin ti jero fe ko
Won ni Lola jawo ní bè
Kii ṣe ọnà rẹ
You're sounding like a clown o máa n pariwo
Se o ra wọn ẹgbẹ rẹ ni
Won ti n s'eniyan
Some are bankers, some engineers
Ise ori ran mi ni mo n je ooo
Mi o s'aye alaye óò
Atewo la ba'la ara ule
A o mo eni to ko ooo
Verse 2
Won ni n ló wa se ṣe
Kí n yẹ tan ra mi
O ra won bisi bukky to n sise bo se n dàn
Won lè enu mi dun in fact odun ju iyo lo po
Awọn kan n'ole ni
O le alapa ma sise
Mẹ ma wo'be mi o se bi pe mo gbodo
Oro ayé mi ko ma maa yenikan