Iranlowo Alailenikan歌词由’Dare Rhapsody演唱,出自专辑《Iranlowo Alailenikan》,下面是《Iranlowo Alailenikan》完整版歌词!
Iranlowo Alailenikan歌词完整版
Mo kigbe si o
Olorun mi
Mo gboju soke si o
Olorun mi
Iranlowo alailenikan
Iwo nikan lo ku mi ku
Wa bomi bi o se bo Elijah lojosi atopo Zarefati
Mo kigbe si o
Olorun mi
A kigbe si o
Olorun awa
A gboju soke si o
Olorun awa
A gboju soke si o
Olorun awa
Iranlowo alailenikan
Iwo nikan loku talaka ku
Wa bowa bi o SE Bo Elijah lojisi atopo Zerifati
A kigbe si o
Olorun awa
Nigeria yi nsan fun wara atoyin
Sugbon enu awon perete lo nro si
Awon kan gbenu ti Nigeria
Won fa omi ara re gbe
Awon kan yobe ti eran Ara Nigeria
Won ripe won je ku egungun
Won o ti e je ki mekunnu ri egun ponla won tun yo sledge hammer
Awon olori Nigeria njakere latori
Awa Ara ilu ntenwo pafeje
Tani o mo peni to nje ajere latori kole funmi nitan je
a o ni ijoba
Eje ka pa okan sodo Eledumare
Iranlowo alailenikan
A kigbe si o
Olorun wa
A gboju soke si o
Olorun awa
Iranlowo alailenikan
Iwo Nikan lo ku talaka ku
Wa bowq bibo se bo Elijah lojosi atopo Zerefati
A kigbe si o
Olorun awa
Bebi bakuro ninu ise ni Yoruba nwi
Ise ti buse
Asiko to fi bo Elijah laginju
Jije mimu nikan nisoro Toni
Elijah ko ni sasun
Sibe oun je ajeyo
Asiko to bo opo Zerefati
Atije atimu nikan nisoro ikoko
Kolobo ororo ko gbe
Amo nitemi bukata ti po
Enu ti fe si
Maseje ki nse alaini ohun gbogbo ti mo nilo
Lati fi gbo bukata mi
Torina
Mo kigbe si o
Olorun mi
Mo gboju some SI o
Olorun mi
Iranlowo alaikenikan
Iwo nikan lo ku mi ku
Wa bomi bi o SE Bo Elijah lojosi atopo Zerefati
Mo kigbe SI o
Olorun mi