Asiko Ti To (Praise Medley)歌词由Choirband CSMC K45 Zaria演唱,出自专辑《Asiko Ma Ti to (It Is Time)》,下面是《Asiko Ti To (Praise Medley)》完整版歌词!
Asiko Ti To (Praise Medley)歌词完整版
Bigi ba dara ninu igbo
To ba duro rere ninu oko
Ti ewe re ba tutu mini mini
Bi ko so eso asan ni
Bigi ba dara o
Bigi ba dara ninu igbo
To ba duro rere ninu oko
Ti ewe re ba tutu mini mini
Bi ko so eso asan ni
Oluwa ko wa kale kaye ojo wa
Oluwa kowa lati ma beru re
Kama file aiye wa ba orun wa je
Ka ranti pe orun o ohun ni ipile wa
Orun lose pataki ju omo leyin Jesu
Ronu ojo ma lo
Oluwa ko wa kale kaye ojo wa
Oluwa kowa lati ma beru re
Kama file aiye wa ba orun wa je
Ka ranti pe orun o ohun ni ipile wa
Orun lose pataki ju omo leyin Jesu
Ronu ojo ma lo
Igba o duro akoko ma ku si dede
Olojo ka jo ronu atisun
Kose rere
Igba o duro akoko ma ku si dede
Olojo ka jo ronu atisun
Kose rere
Kama file aiye wa ba orun wa je o
Ka ranti pe orun o ohun ni ipile wa
Orun lose pataki ju omo leyin Jesu
Ronu ojo ma lo
Oluwa ko wa kale kaye ojo wa
Oluwa kowa lati ma beru re
Oluwa ko wa kale kaye ojo wa
Oluwa kowa lati ma beru re
Kama file aiye wa ba orun wa je
Ka ranti pe orun o ohun ni ipile wa
Orun lose pataki ju omo leyin Jesu
Ronu ojo ma lo
Ojo nla kan ma bo
To lu siro yio de
Gbogbo eniyan ni yio ri
Aiye yio wa riri
Igbagbo re ada
Wo ti ko mo Olorun
To fe da se igbekele
To ko Oluwa sile
Eh eh eh aiye yi lo
Eh eh eh aiye yi lo
Igba o duro denikan
Sise rere nitori
Aiye yi lo
Eh eh eh aiye yi lo
Eh eh eh aiye yi lo
Igba o duro denikan
Sise rere nitori
Aiye yi lo
Gbogbo wa
Gbogbo wa
Gbogbo wa o o
Gbogbo wa
Lao jiyin ise owo wa nikeyin o
Gbogbo wa
Gbogbo wa ni o
Gbogbo wa
Lao jiyin
Gbogbo wa
Ati okunrin ati
Obirin ati omode wa o
Gbogbo wa
Gbogbo wa
Lao jiyin
Gbogbo wa
Gbogbo wa pata
Gbogbo wa ni gbogbo wa ni o
Gbogbo wa
Gbogbo wa
Lao jiyin
Gbogbo wa
Ati emi ati iwo
Gbogbo wa lao jiyin o
Gbogbo wa
Gbogbo wa
Lao jiyin
Gbogbo wa
Ohun to ba se
Lao fi se idajo re o
Gbogbo wa
Gbogbo wa
Lao jiyin
Gbogbo wa
Gbogbo wa gbogbo wa
Pata lao jiyin ise owo wa o
Gbogbo wa
Gbogbo wa
Lao jiyin
Gbogbo wa